Jabọ ìfàsẹ́ · Rahoto kama · Jabọ ìfàsẹ́ · Kọọ njide · Report say dem arrest person
Ẹni kan ni wọ́n mú. Sọ fún paralegal.
Ìbéèrè mẹ́rin. Kò sí àkọọlẹ. Paralegal láti ọ́fíìsì ìrànlọ́wọ́ òfin yóò ṣàyẹ̀wò ìròyìn náà, ó sì lè pè ọ́. Èyí kì í ṣe ìmọ̀ràn òfin, kò sì ní fi ohunkóhun sílẹ̀ ní kòtù.